Nigeria

Oriki Eko – Lyrics & Mp3

 

Download Oriki Eko (Mp3)

Oriki Isale-Eko ….

This Panegyric Is Dedicated To Our ‘Islanders’ Members

Eko Akete Ilu Ogbon

Eko Aromi sa legbe legbe

Eko aro sese maja

Eko akete ilu okun alagbalugbu omi,

Ta lo ni elomi l’eko? ebiwon pe talo ni abata butu baba omikomi, talo laabata buutu baba odo kodo

Eko adele ti angere nsare ju elese meji lo

Eni to ba lo si ilu eko tiko gbon, bo re oke okun ko legbon mo

Afefe toni pon wa ni bebe okun ti yin, faaji to ni pan wa ni bebe osa

Eko omo osha nio ose, mase kutere, osha n gbobi, kutere n gbori

Eyin lomo afinju woja marin gbendeke, obun woja n wapa sio sio

Eyo o Aye’le Eyo o, Eyo baba n teyin to n fi golu n sere, eyin oni sanwo onibode, odilee

Kile tungbe? owo owo latungbe

Kile fise? aso aso la o fira

Aso kilera? eye eye oyinbo

Etun jale o, etun jale oko nlo

Eh eh oloba eeh oloba

Oloba mijo aya re nma rijo sebi oba eh eh Oloba

Bi oju o ba ti ehin igbeti, oju o ni t’eko ile

Download Latest Mixtapes